USA-based Nigerian music minister, songwriter, and worshiper, Ewaoluwa Ayoola releases her debut single titled “MIMO” featuring BBO.
Revelation 4:8 "Each of the four living creatures had six wings and was covered with eyes all around, even under its wings. Day and night they never stop saying: “’Holy, holy, holy is the Lord God Almighty,’ who was, and is, and is to come.”

MIMO LYRICS - EWAOLUWA FT. BBO
Awon ti won yin Olorin nigbgbo igba won joko won duro niwaju ite re ko sohun ti won se
won yin won ke mimo si atobiju si atofarati bi oke
moni mo nso ti awon ti o wo aso funfun ti ogun ti olopin
won ki Oba ti olafiwe
won ki eniwaju ti nsiwaju ogun
won ki eni eyin ti nkeyin ogun
won ki eni nla ti n komo ye loju ogun
awon ti o jade ninu iponju ti wonsi so won di funfun ninu eje odo agatuan
won nbe niwaju ite olorun won si eniti ojoko lori ite

ton siji bowon ebi ole pawon beni oungbe ole gbe won
won korin titun ka niwaju ite na ati niwaju awon eda
won korin titun ka niwaju ite na ati niwaju awon eda
alaye merin ati awon agbagba merinlelogun o
kosi eni ti ole mo orin na afi awon oke meje
kosi eni ti ole mo orin na afi awon oke meje
ole egbaaji eniyan eniyan ti ati rapada ninu aye
motun so ti angeli to fo lagbedemeji orun
mojuba eniti o da orun ataye okun ati gbogbo orisun omi
mo nko mimo si eni ti ote iyn isreali do
Olorun to gun kuku leshin
motun so ti angeli to fo lagbedemeji orun
mojuba eniti o da orun ataye okun ati gbogbo orisun omi
mo nko mimo si eni ti ote iyn isreali do
Olorun to gun kuku leshin
Olorun o ega fio fio eo lafiwe be leo lakawe
ina ti njo ni papa ti igbe orun oke to ga ju oke lo o
modarapo mo awon ti orun
awon ti won ko mimo o won se mimo
mimo lawon torun ke o awon to woso fun fun togun tion lopin
wonke mimi wonko mimi
mimo mimo lawon torun ke
awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo
awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo
BBO
Si eni mimo to nse mimo to wu iwa mimo o
tawon agbagba merinlelogun nko mimo mimo si lojojumo eru re nba mi o
emi tokoja imisi omo eniyan ipa tobori gbogbo
ipa eda patapata bi ose wa ni gbara to
ofi agbara re ni aye lara o eru re mba mi o e
eyin lalasepe ayin lalasegbe eyin ni olorun to nse to muje oo
gbogbo agbara laye ati orun inu ikawo re lowa o
olorun odanikan sejoba bose wa je eni mimo to
otun fi aye sile o fun oni doti to fe sunmo o felese to fe mo e
se kin maparo olori aye olgun ajoobo o eru re nba mi ooo ee
se kin maparo olori aye olgun ajoobo o eru re nba mi ooo ee
awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo
awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare
mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo
mimo re oba ogo mimo re oba eda mimo re oba ogo
ogo oo mimo re oba ogo (2ce)